Jer 2:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sibẹ iwọ wipe, alaiṣẹ̀ li emi, ibinu rẹ̀ yio sa yipada lọdọ mi. Sa wò o, emi o ba ọ jà, nitori iwọ wipe, emi kò ṣẹ̀.

Jer 2

Jer 2:29-37