Jer 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mimọ́ ni Israeli fun Oluwa, akọso eso oko rẹ̀, ẹnikẹni ti o fi jẹ yio jẹbi; ibi yio si wá si ori wọn, li Oluwa wi.

Jer 2

Jer 2:1-13