Jer 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn enia mi ṣe ibi meji: nwọn fi Emi, isun omi-ìye silẹ, nwọn si wà kanga omi fun ara wọn, kanga fifọ́ ti kò le da omi duro.

Jer 2

Jer 2:7-18