Jer 19:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jeremiah wá si Tofeti, nibiti Oluwa ti rán a lati sọ asọtẹlẹ; o si duro ni àgbala ile Oluwa; o si wi fun gbogbo awọn enia pe,

Jer 19

Jer 19:4-15