Jer 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ba ṣe ibi niwaju mi, ti kò si gbà ohùn mi gbọ́: nigbana ni emi o yi ọkàn mi pada niti rere, eyiti mo wi pe, emi o ṣe fun wọn.

Jer 18

Jer 18:7-16