Jer 17:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn kò gbọ́, nwọn kò si tẹti silẹ, nwọn mu ọrun wọn le, ki nwọn ki o má ba gbọ́, ati ki nwọn o má bà gba ẹ̀kọ́.

Jer 17

Jer 17:20-27