Jer 16:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi niti ọmọkunrin ati ọmọbinrin ti a bi ni ihinyi, ati niti awọn iya wọn ti o bi wọn, ati niti awọn baba wọn ti o bi wọn ni ilẹ yi.

Jer 16

Jer 16:1-5