Jer 16:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti oju mi mbẹ lara ọ̀na wọn gbogbo: nwọn kò pamọ kuro niwaju mi, bẹ̃ni ẹ̀ṣẹ wọn kò farasin kuro li oju mi.

Jer 16

Jer 16:7-21