Jer 16:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, sa wò o, Bayi li Oluwa wi, ọjọ mbọ̀, ti a kì o wi mọ́ pe, Oluwa mbẹ ti o mu awọn ọmọ Israeli jade kuro ni ilẹ Egipti;

Jer 16

Jer 16:7-21