Jer 14:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn kẹtẹkẹtẹ-igbẹ duro lori oke wọnni, nwọn fọn imu si ẹfũfu bi ikõko, oju wọn rẹ̀ nitoriti kò si koriko.

Jer 14

Jer 14:1-10