Jer 14:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. EYI li ọ̀rọ Oluwa ti o tọ̀ Jeremiah wá nipa ti ọdá.

2. Juda kãnu ati ẹnu-bode rẹ̀ wọnnì si jõro, nwọn dudu de ilẹ; igbe Jerusalemu si ti goke.

Jer 14