Jer 13:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe lẹhin ọjọ pupọ, Oluwa wi fun mi pe, Dide, lọ si odò Ferate, ki o si mu amure nì jade, ti mo paṣẹ fun ọ lati fi pamọ nibẹ.

Jer 13

Jer 13:2-12