Jer 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BAYI li Oluwa wi fun mi pe: Lọ, ki o si rà àmure aṣọ ọgbọ̀, ki o si dì i mọ ẹgbẹ rẹ, ki o má si fi i sinu omi.

Jer 13

Jer 13:1-9