Jer 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ti kọ̀ ile mi silẹ, mo ti fi ogún mi silẹ; mo ti fi olufẹ ọ̀wọn ọkàn mi le ọta rẹ̀ lọwọ.

Jer 12

Jer 12:5-12