Jer 11:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa pè orukọ rẹ ni igi Olifi tutu, didara, eleso rere: ṣugbọn nisisiyi o fi ariwo irọkẹkẹ nla dá iná lara rẹ̀, ẹka rẹ̀ li o si faya.

Jer 11

Jer 11:7-23