Jer 10:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn oluṣọ agutan ti di ope, nwọn kò si wá Oluwa: nitorina nwọn kì yio ri rere, gbogbo agbo wọn yio si tuka.

Jer 10

Jer 10:18-25