Jer 10:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa wi, Ẹ máṣe kọ́ ìwa awọn keferi, ki àmi ọrun ki o má si dãmu nyin, nitoripe, nwọn ndamu awọn orilẹ-ède.

Jer 10

Jer 10:1-11