Jer 10:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

On ti da aiye nipa agbara rẹ̀, on ti pinnu araiye nipa ọgbọ́n rẹ̀, o si nà awọn ọrun nipa oye rẹ̀.

Jer 10

Jer 10:8-16