Jak 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wura on fadaka nyin diparà; iparà wọn ni yio si ṣe ẹlẹri si nyin, ti yio si jẹ ẹran ara nyin bi iná. Ẹnyin ti kó iṣura jọ dè ọjọ ikẹhin.

Jak 5

Jak 5:1-10