Jak 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikẹni ṣe aisan ninu nyin bi? ki o pè awọn àgba ijọ, ki nwọn si gbadura sori rẹ̀, ki nwọn fi oróro kùn u li orukọ Oluwa:

Jak 5

Jak 5:5-19