Jak 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori olukuluku ẹda ẹranko, ati ti ẹiyẹ, ati ti ejò, ati ti ohun ti mbẹ li okun, li a ntù loju, ti a si ti tù loju lati ọwọ ẹda enia wá.

Jak 3

Jak 3:1-12