Jak 2:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ẹniti o wipe, Máṣe ṣe panṣaga, on li o si wipe, Máṣe pania. Njẹ bi iwọ kò ṣe panṣaga, ṣugbọn ti iwọ pania, iwọ di arufin.

Jak 2

Jak 2:10-20