Jak 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ba kù ọgbọn fun ẹnikẹni, ki o bère lọwọ Ọlọrun, ẹniti ifi fun gbogbo enia ni ọ̀pọlọpọ, ti kì isi ibaniwi; a o si fifun u.

Jak 1

Jak 1:1-6