Jak 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ fi gbogbo ẽri ati buburu aṣeleke lelẹ li apakan, ki ẹ si fi ọkàn tutù gbà ọ̀rọ na ti a gbin, ti o le gbà ọkàn nyin là.

Jak 1

Jak 1:17-27