Jak 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin mọ eyi, ẹnyin ará mi olufẹ; ṣugbọn jẹ ki olukuluku enia ki o mã yara lati gbọ́, ki o lọra lati fọhùn, ki o lọra lati binu:

Jak 1

Jak 1:12-23