Jak 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibukún ni fun ọkunrin ti o fi ọkàn rán idanwò: nitori nigbati o ba yege, yio gbà ade ìye, ti Oluwa ti ṣe ileri fun awọn ti o fẹ ẹ.

Jak 1

Jak 1:10-14