Isa 8:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ki ọmọ na to ni oye ati ke pe, Baba mi, ati iya mi, ọrọ̀ Damasku ati ikogun Samaria ni a o mu kuro niwaju ọba Assiria.

Isa 8

Isa 8:2-9