Isa 8:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, emi ati awọn ọmọ ti Oluwa ti fi fun mi wà fun àmi ati fun iyanu ni Israeli, lati ọdọ Oluwa awọn ọmọ-ogun wá, ti ngbe òke Sioni.

Isa 8

Isa 8:13-22