Isa 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

PẸLUPẸLU Oluwa wi fun mi pe, Iwọ mu iwe nla kan, ki o si fi kalamu enia kọwe si inu rẹ̀ niti Maher-ṣalal-haṣ-basi.

Isa 8

Isa 8:1-7