Isa 66:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si jade lọ, nwọn o si wò okú awọn ti o ti ṣọtẹ si mi: nitori kokoro wọn kì yio kú, bẹ̃ni iná wọn kì yio si kú; nwọn o si jẹ ohun irira si gbogbo ẹran-ara.

Isa 66

Isa 66:22-24