Isa 66:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori gẹgẹ bi awọn ọrun titun, ati aiye titun, ti emi o ṣe, yio ma duro niwaju mi, bẹ̃ni iru-ọmọ rẹ ati orukọ rẹ yio duro, li Oluwa wi.

Isa 66

Isa 66:13-24