Isa 66:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi mọ̀ iṣẹ ati ìro wọn: igba na yio dé lati ṣà gbogbo awọn orilẹ-ède ati ahọn jọ, nwọn o si wá, nwọn o si ri ogo mi.

Isa 66

Isa 66:16-19