Isa 65:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kì yio ṣiṣẹ lasan, nwọn kì yio bimọ fun wahala: nitori awọn ni iru alabukun Oluwa ati iru-ọmọ wọn pẹlu wọn.

Isa 65

Isa 65:21-24