Isa 6:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi kàn mi li ẹnu, o si wipe, Kiyesi i, eyi ti kàn etè rẹ, a mu aiṣedede rẹ kuro, a si fọ ẹ̀ṣẹ rẹ nù.

Isa 6

Isa 6:2-8