Isa 59:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori irekọja wa npọ̀ si i niwaju rẹ, ẹ̀ṣẹ wa njẹri gbè wa, nitori irekọja wa mbẹ lọdọ wa, niti aiṣedede wa, awa mọ̀ wọn.

Isa 59

Isa 59:11-19