Isa 57:20-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Ṣugbọn awọn enia buburu dabi okun ríru, nigbati kò le simi, eyiti omi rẹ̀ nsọ ẹrẹ ati ẽri soke.

21. Alafia kò si fun awọn enia buburu, ni Ọlọrun mi wi.

Isa 57