Isa 56:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Afọju li awọn alore rẹ̀: òpe ni gbogbo wọn, odi ajá ni nwọn, nwọn kò le igbó, nwọn a ma sùn, nwọn ndubulẹ, nwọn fẹ ma tõgbé.

Isa 56

Isa 56:5-12