Isa 53:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

A mu u jade lati ibi ihamọ on idajọ: tani o si sọ iran rẹ̀? nitori a ti ke e kuro ni ilẹ alãye: nitori irekọja awọn enia mi li a ṣe lù u.

Isa 53

Isa 53:6-12