Isa 51:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori kòkoro yio jẹ wọn bi ẹ̀wu, idin yio si jẹ wọn bi irun agutan: ṣugbọn ododo mi yio wà titi lai, ati igbala mi lati iran de iran.

Isa 51

Isa 51:5-17