Isa 51:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi Oluwa Ọlọrun rẹ ti o pin okun ni iyà, eyi ti ìgbi rẹ̀ nhó; Oluwa awọn ọmọ-ogun ni orukọ rẹ̀.

Isa 51

Isa 51:7-23