Isa 5:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti ọfà wọn mu, ti gbogbo ọrun wọn si kàn, a o ka patakò ẹsẹ ẹṣin wọn si okuta akọ, ati kẹkẹ́ wọn bi ãja.

Isa 5

Isa 5:23-30