Isa 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn enia mi lọ si oko-ẹrú, nitoriti oye kò si, awọn ọlọla wọn di rirù, ati ọ̀pọlọpọ wọn gbẹ fun orùngbẹ.

Isa 5

Isa 5:5-18