Isa 48:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nwọn npè ara wọn ni ti ilu mimọ́ nì, nwọn si gbé ara wọn le Ọlọrun Israeli: Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀.

Isa 48

Isa 48:1-9