Isa 48:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọwọ́ mi pẹlu li o si ti fi ipilẹ aiye sọlẹ, atẹlẹwọ ọ̀tun mi li o si na awọn ọrun: nigbati mo pè wọn, nwọn jumọ dide duro.

Isa 48

Isa 48:4-21