Isa 43:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi li Oluwa Ọlọrun rẹ, Ẹni-Mimọ Israeli, Olugbala rẹ: mo fi Egipti ṣe irapada rẹ, mo si fi Etiopia ati Seba fun ọ.

Isa 43

Isa 43:1-10