Isa 41:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tali o ti dá a ti o si ti ṣe e, ti o npè awọn iran lati ipilẹṣẹ̀ wá? Emi Oluwa ni; ẹni-ikini, ati pẹlu ẹni-ikẹhìn; Emi na ni.

Isa 41

Isa 41:1-12