Isa 40:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

On ni ẹniti o joko lori òbíri aiye, gbogbo awọn ti ngbe ibẹ si dabi ẹlẹngà; ẹniti o ta ọrun bi ohun tita, ti o si nà wọn bi àgọ lati gbe.

Isa 40

Isa 40:16-25