Isa 39:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Kini nwọn ri ni ile rẹ? Hesekiah si dahùn pe, Ohun gbogbo ti o wà ni ile mi ni nwọn ti ri: kò si nkankan ti emi kò fi hàn wọn ninu iṣura mi.

Isa 39

Isa 39:1-8