Isa 38:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI ọjọ wọnni Hesekiah ṣaisàn de oju ikú. Woli Isaiah ọmọ Amosi si wá sọdọ rẹ̀, o si wi fun u pe, Bayi ni Oluwa wi, Palẹ ile rẹ mọ́: nitori iwọ o kú, o ki yio si yè.

2. Nigbana ni Hesekiah yi oju rẹ̀ si ogiri, o si gbadura si Oluwa.

Isa 38