Isa 34:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ibinu Oluwa mbẹ lara gbogbo orilẹ-ède, ati irúnu rẹ̀ lori gbogbo ogun wọn: o ti pa wọn run patapata, o ti fi wọn fun pipa.

Isa 34

Isa 34:1-10